Iba ree nima faayee mii ju
Sinsin ooo lemi a fii gbamise
Sebi yen naani iyen gangan shaa loda mii fun
Eni ayeraye too nii gba mii oo mofogoo foruko ree
Afuye geegee tiko seegbe, jibini jibinii bii atee ileke
kabiesi mosebare ooo oba too juu gbogbo oba loo (2ce)
Iba ooo ibaa ooo
Mosebare ooo mosebare moforii balee mogbowoo sokee kabiesi
moo sebare oba too juu gbogbo oba loo
Mosebare ooo mosebare ree nirele okan miiii nimo waari
Kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo
Emiin sebare ooo mosebare
Moforii balee mogbowoo sokee kabiesi moo sebare oba too juu
gbogbo oba loo
Taloo lee soo talo lee kaawon awon irawo towa loju orun egbe
isiro lewon kee sofun waa
Awon erupe inu okun talo lee soo talo moo yee ewa iseda toyi
waa kaa
Iyanu fun dudu Iyanu fun funfun
Ose feni too gban ati enii too goo
Kabiesi ooo mosebare ree oba too juu gbogbo oba loo
Afuye geegee tii ooo seegbe jibini jibinii bii atee ileke
Kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo
Mosebare ooo mosebare ree oba too juu gbogbo oba loo
Gbogbo ayee gboun sokee won sebare
Oun gbogbo seba fun ooo mofogoo foruko ree
Oju mii tiri eti mii tii gbooo Iyanu ree yii ayee kaa
Mogboo ninu eri awon eyan mimo
Mori ninu itan emi gangan nii itan
Gbogbo isee ree daadaadaa niii aburu kankan ooo too doo ree
waa
Oun gbogbo loleyii pade sugbon rara toodoodoo ree koo
Kabiesi ooo mosebare ree ooo oba too juu gbogbo oba loo
Afuye geegee tii ooo seegbe jibini jibinii bii atee ileke
Kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo
Mosebare ooo mosebare ree moforii balee mogbowoo sokee
kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo
Mosebare ooo mosebare nirele okan miiii mowarii
Kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo
Oba too juu gbogbo oba loo kabiesi moo sebare Oba too juu
gbogbo oba loo
Emi ooo maa fiibukun foruko ree
Oba too juu gbogbo oba loo
Nigba gbogbo lemi ooo fiiyin fun ooo see
Oba too juu gbogbo oba loo
Oluwa oro ree yii aye kaa
Oba too juu gbogbo oba loo
Mojewo ree Mojewo iwo nikan loluwa ooo oba too juu gbogbo
oba loo
You are beautiful beyond description ewa ree koja ogbon orii
miiii
Oba too juu gbogbo oba loo
You are wonderful beyond comprehension oro ree koja oyee mii
Oba too juu gbogbo oba loo.
No comments:
Post a Comment
Visit Itune for the audio and Youtube for the video of this song..
All lyrics on this blog are properties of the artists and are provided for educational purposes.