Bami se otito mo fe o tooto
Bami se ododo mo fe o pelu ododo
Bami se otito ololufe mo fe o tooto
Bami se ododo mo fe o pelu ododo
Bi ogiri o ba lanu alangba o le wo ogiri

Eleda lo yan wa papo esu koni ya wa o
Ife bi eji owuro, lati agbala Eledumare lo ti se wa
Ife ti o toro minimini, ti abawon aye kan kole baje o
Ololufe feranmi lai se etan

Ore okan mi feranmi lai se etan
Femi bi oju ti nfe mu, femi bi irun ti nfe ori
Femi bi ehin ti nfe enu, femi ti emi ti emi
Femi ti okan ti okan, femi ti ara ti ara
Ololufe feranmi lai se etan
Femi bi oju ti nfe mu, femi bi irun ti nfe ori
Femi bi ehin ti nfe enu, femi ti emi ti emi
Femi ti okan ti okan, femi ti ara ti ara
Ololufe feranmi lai se etan
(Ife bi eji owuro unnnnnnnnnnnnh)
(Ife e uunnnnnnnnnh)
Duro timi o ololufe, ife ti ko la bukun ni ki o bami lo
Duro timi o ololufe, ife ti ko l'abawon ni ki o bami lo
Ife bi eji owuro, lati agbala Eledumare lo ti se wa
Ife ti o toro minimini, ti abawon aye kan kole baje o
Ololufe feranmi feranmi lai se etan
Femi bi oju ti nfe mu, femi bi irun ti nfe ori
Femi bi ehin ti nfe enu, femi ti emi ti emi
Femi ti okan ti okan, femi ti ara ti ara
Ololufe feranmi lai se etan
Ama ni owo lowo, ama bi omo le omo,
Ama se ayo mo ayo, ama se ola mo ola
Kasa mu ife Eledumare se lai se etan
Ife bi eji owuro, lati agbala Eledumare lo ti se wa
Ife ti o toro minimini, ti abawon aye kan kole baje o
Ololufe feranmi lai se etan
Ife bi eji owuro, lati agbala Eledumare lo ti se wa
Ife ti o toro minimini, ti abawon aye kan kole baje o
Ololufe feranmi feranmi feranmi
Gba moran mi ololufe mi, oluranlowo lafi mi se fun o lati
orun wa
Fi eti si amoran mi, ayanmo wa jo ra won
Oluranlowo la fi mi se fun o lati orun wa
Ka jorin ka sogo fun oruko Olorun
Alabarin la fi mi se fun o lati orun wa
Mokan kuro ninu asan aye etan o da nkankan fun ni
Ife ati ope lole mu wa laye ja lai ni abawon
Mokan kuro ninu asan aye etan o da nkankan fun ni
Ife ati ope lole mu wa laye ja lai l'abawon
Ife bi eji owuro, lati agbala Eledumare lo ti se wa
Ife ti o toro minimini, ti abawon aye kan kole baje o
Ololufe feranmi lai se etan
Ife bi eji owuro, lati agbala Eledumare lo ti se wa
Ife ti o toro minimini, ti abawon aye kan kole baje o
Ololufe feranmi lai se etan
Duro timi o ololufe ife ti ko l'abukun ni ki o ba mi lo
Duro timi o ololufe ife ti ko ni etan rara ni ki o ba mi lo
Duro timi o ololufe ife ti ko l'abukun ni ki o ba mi lo
Duro timi o ololufe ife ti ko l'abukun ni ki o ba mi lo
Duro timi o ololufe ife ti o l'abukun ni ki o ba mi lo.
No comments:
Post a Comment
Visit Itune for the audio and Youtube for the video of this song..
All lyrics on this blog are properties of the artists and are provided for educational purposes.