Friday, April 24, 2020

Akosile Lyrics - Sola Allyson Obaniyi

Akosile ti duro akosile o le tase oun toluwa base eda kan
kole yi
Pada ibi ori n gbe ni lo kese ma si ni lona oun to wun
eleduwa lo le
Yan fun wa atibi atire ton sele lala eda kole ye e e akosile
ti duro
Kole tase o o o, ayanmo eda ti duro kirakita o dola laye
gbogbo eto
Olorun kose ni tole ba tun to gbogbowa lan sare kiri pe ka
lola ka
Jeniyan sugbon ta lole mo ibi ori dawun si atibi atire ton
sele lala
Eda kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se,
Wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye
Mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.
Kadara eda ti duro ife eleda o le ye lai ona ti o ba wun
olorun oun
Lole mu ese eda to ori e o dade ofe jo ba o wa n ba yanmo
jijakadi
Boti wun e ni to dale lose n foyin si atibi atire ton sele
lala eda
Kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o,
Eniyan ma yo ra leun koya gba folorun lo to womo meji tabi
lojo kan
Ayanmo ototo loyan onise ika n sorire onise re wan to si Awa
bi
Olorun lere bo se je boti wun oluwa lon soro kose ni tole da
lejo
Akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se wa ba mi se o
baba
Koma se le mo mi kaye mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi
da.
Oro olorun ede ni ileri re ko le ye lai oun ti oluwa ba pinu
ife ota
Kan o le pada oti pinu pe ki sorire pe ki lola ki n jeniyan
oun
Toluwa ba ko ko seni to le yi bo ti wun oluwa lon soro oun
lo layo
Ati ola akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se wa ba mi
se,
Wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye mi ma koro bi ewuro
ara ire
Ni kofimi da, wa ba mi se mo bebe,
Iwo lo ran mi wa ba mi se kaye mi
Ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.


Lyrics provided and carefully edited just for you. All song lyrics belongs to the artists and are provided for educational purposes and basically for African Gospel songs only. Hope the lyrics of your favorite song is correct?

No comments:

Post a Comment

Visit Itune for the audio and Youtube for the video of this song..
All lyrics on this blog are properties of the artists and are provided for educational purposes.

Correct Lyrics © 2020 Africanglyrics No privacy infringement intended