Friday, April 24, 2020

Olorun Awon Omo Ogun Lyrics - Sola Allyson Obaniyi

Ògo ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ògo Ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọba tó f'na hàn wá
Ọba tó lẹ' mi wá
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun
Ọba tó f'na hàn wá
Ọba tó lẹ' mi wá o
Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
Níbi tó lẹ' wá julo Ní Ìwọ gbé
Lórí obiiri ayé níwọ̀ wá o
Imọ'lẹ' láṣọ re
Ọlá lọ fi ṣá'gbara
Níbi tó lẹ' wá julo ni ìwọ gbé
Lórí obiiri ayé ni'wo wá o
Imọ'lẹ' láṣọ rẹ
O ó Ọlá lọ fi ṣá sọ bora
Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
Ọba tó lẹ' mi mi
Ọba tó ní gbà mi
Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
Ọba tó lẹ' mi mi
Ọba tó ní gbà mi
Ahhhhh Ahhhhh
Ìwọ lọ lè mi ò
Ìwọ lo nígbà mi
Ìṣẹ'lẹ' inú ìṣẹ̀dá ṣá'fihàn àgbàrá rẹ
Àwọn ohùn tàri ṣáá fihan ìṣe rẹ o
Pẹ'lú ifilelẹ' tí ó lè Páráda láì láì
Àrà ọwọ rẹ ni gbogbo wọ́n
Ṣe bí èyí tàri là ń wi
Àwọn ohùn tá a ò lè rí má bùsan yeye
Àìmọye làwọn tá kò mo l' àrà
Ẹ'dá ó lè ṣá kàwé wọn
Ibí tó lẹ' wá julo ni ìwọ gbé
órí obiiri ayé ni'wo wá o
Imọ'lẹ' láṣọ rẹ
O ó Ọlá lọ fi ṣá sọ bora
Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
Ọba tó lẹ' mi mi
Ọba tó ní gbà mi
Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi ò eh
Ọba tó lẹ' mi mi
Ọba tó ní gbà mi
Ògo ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ògo Ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ọba tó fún ní lé mi ọba tó lé mi ẹni tó
lé mi gàn gàn
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ogo rẹ pọ púpò ṣe bí èyí tàle fara gbà
mú là ń jẹ fani ẹ
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun
Call: Àìmọye àwọn èyí tá'kólé mọ' bíi kò
ṣé bí a gbà sunmọ ibùgbé rẹ
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ìyanu rẹ kọjá a fẹnu sọ ìwọ'n bá ti
ọgbọ'n orí lè gbé là ń ṣá pé júwe fún
Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
Call: Olúwa àwọn ọmọ ogún kọjá àpèjúwe kò
ṣe ní tó lè mọ ṣe rẹ
Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
Call: ẹni bẹ lórí ìtẹ' á sì wà síbè sì bí ó
ti wà láì láì ni yẹn ìyípadà kàn ó sì
Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogun
Call: Gbogbo ògo gbogbo ọlá gbogbo ìjọba tìrẹ
ṣá ní
Reap: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún



Lyrics provided and carefully edited just for you. All song lyrics belongs to the artists and are provided for educational purposes and basically for African Gospel songs only. Hope the lyrics of your favorite song is correct?

No comments:

Post a Comment

Visit Itune for the audio and Youtube for the video of this song..
All lyrics on this blog are properties of the artists and are provided for educational purposes.

Correct Lyrics © 2020 Africanglyrics No privacy infringement intended